Related Articles
Random (II)
Igba die loku
orekelewa eyin fun jowo mi –
aji fi ojo gbogbo dara bi egbin,
ma binu si mi wipe mio ti de,
kirakita ti o ma di ola ni mo’n ba ka,
won tan mi wipe owo o shey koko,
shugbon emi o ni tan ara mi.
a’pon ba epo re mi Ewadunni Eriayomi,
omo akin ni mi, fi ife re tomide si ahin,
la ko de ni mo wa bi opolo alajo Somolu,
igba die lo ku ti mo fi ma to e wa si ile yin,
igba die loku, Ewatomilayo mi, ololufe mi.
Tomide Abdul
Click Next To Continue Reading This Post



